Ko S’oba Bire by Jumoke Odusole Lyrics

Ko S’oba Bire by Jumoke Odusole Lyrics

Chorus:
You are Jesus (2×)
Laye lorun
Iwo ni kosoba bire (2×)

Verse 1:
Call
: Arugbo ojo (Ancient of days)
Resp: Iwo ni
Call: Alagbada Ina (The one clothes in fire)
Resp: Iwo ni

Call: Eleru niyin (Fearful to be praised)
Resp: Iwo ni kosoba biire

Chorus:
You are Jesus (2×)
Laye lorun
Iwo ni kosoba bire (2×)

Verse 2:
Call
: Ebube dike (Glorious warrior)
Resp: Iwo ni
Call: Nmalite na gwugwu (Beginning and the end)
Resp: lwo ni

Call: Odogwu akataka (Fearless warrior)
Resp: lwo ni kosoba bire.

Chorus:
You are Jesus (2×)
Laye lorun
Iwo ni kosoba bire (2×)

Verse 3:

Resp: Ubangiji (The Supreme being)
Resp: lwo ni
Call: Sarkin sarakuna (King of kings)
Resp: Iwo ni

Call: Almasihu (Messiah)
Resp: Iwo ni kosoba biire

Bridge:
Jeki ase re bere kase re bere
Lori aye mi (2x)

Chant:
Kabio osi
(Unquestionable)
Alagbada Ina
(The one clothes with fire)
Alawotele oorun
(He that is full of light)
Oba awon oba
(King of kings)

Olori aye gbogbo
(Ruler of the whole universe)
Talale fi o we
(Who can be compared with you)
Ni gbogbo aye
(In all the earth)
Mo wo kiri, koseni biire
(I searched all over, no one like you)

Okan lana, okan Loni, okan titi ayeraye
(The same yesterday, today and forever)
Oba tan saya
(The King we run to)
Gbanigbani tin gba kekere, tin gba alagbara
(The deliverer, that delivers the youngest and the strongest)
Apata aidigbolu