
Ife Eyi Po by Adediran Tolulope Lyrics
Chorus:
Ife eyi ma po
Ife to tobi
Ife eyi ma po
Ife o laatoke wa
Verse:
Kini moje, Tani mi na
Tofi fe mi, Lapoju Baba o
Kini moje, Tani mina
Tofi ku funmi ni Kafari
Chorus:
Ife eyi ma po
Ife to tobi
Ife eyi ma po
Ife o laatoke wa
Vamp:
Ife ee ooo
Ife o laatoke wa
Ife ti ko labawon o
Ife o laatoke wa
Ife alailegbe oo
Ife o laatoke wa
Me ma riru ife eyi ri o
Ife o laatoke wa
Me ma riru ife eyi ri o
Ife o laatoke wa