Bi Gbogbo Irun Ori Mi Lyrics

Bi Gbogbo Irun Ori Mi Lyrics
Bi Gbogbo Irun Ori Mi Lyrics

Lyrics

Irun Ori Mi (Koto Lati Yin Baba Logo) – Enakeno

Bí gbogbo ooo

Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
Kòtó ooo

Bí gbogbo irun orí miii

VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
Kòtó kòtò láti yín Bàbá logo
Kòtó ooo

VOICE: Hallelujah, Thank You Lord Jesus.